Gospel Songs

Jesu – Nikki Laoye Ft. Cwesi Oteng (Mp3 and Lyrics)

Jesu by Nikki Laoye Ft. Cwesi Oteng Mp3 and Lyrics

Download Jesu By Nikki Laoye Ft. Cwesi Oteng

[download id=”3839″]

Jesu Lyrics by Nikki Laoye Ft. Cwesi Oteng

[Verse 1]
Jesu olufe okan mi
Jesu Olugbala okan mi
O ta eje re sile
Fun irapada mi

[Chorus]
Ibukun atope ni foruko re titilai
Iyin atogo ni, forukore titilai

[Verse 2]
Jesu mi olugbeja mi
Jesu loluso aguntan mi
O wa pelu mi nigba gbogbo
O rin pelu mi emi ki yo beru

[Chorus]
Ibukun atope ni foruko re titilai
Iyin atogo ni forukore titilai

Ibukun atope ni foruko re titilai
Iyin atogo ni forukore titilai

Ibukun atope ni foruko re titilai
Iyin atogo ni forukore titilai

Ibukun atope ni foruko re titilai
Iyin atogo ni forukore titilai

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *