Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise (Mp3, Lyrics)

Download Loro Lero Ati Nise Mp3 by Tope Alabi

Award winning Nigerian Gospel music minister, Tope Alabi unveil a new song “Loro Lero Ati Nise” off her Hymnal Vol. 1 Album.

Video : Loro Lero Ati Nise by Tope Alabi

Loro Lero Ati Nise Lyrics by Tope Alabi

[Verse 1]
Emi ofe o oluwa, agbara a’tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise

[Chrous]
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise

[Verse 2]
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owo’tun re
Iranwo re yo mumi d’ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise

  Tope Alabi - Opin Irin Ajo (Remix)

[Verse 3]
Emi o mayo s’oluwa, oba ati ase mi
Fi’bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola at’ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise

Leave a Comment