Kaabo – Adeyemi Oluwadamilare (Mp3 and Lyrics)

Download Kaabo Mp3 by Adeyemi Oluwadamilare

[download id=”6521″]

Kaabo Lyrics by Adeyemi Oluwadamilare

Lead: Kaabo o kaabo o s’aye o
All: Emmanueli kaabo o s’aye o/2X
Lead: Olutunu wa kaabo o s’aye o
All: Emmanueli kaabo o s’aye o
Lead: Oludande wa kaabo o s’aye o
All: Emmanueli kaabo o s’aye o

[Verse 1]
Oba t’abi fun wa nitori t’emi ati re o wa s’aye o lati gbawa la
ninu ese wa olutunnu wa ni olusegun funwa alaabo wa ni
Emmanueli kaabo o s’aye o

[Verse 2]
Unto us a child is born a child is given,He shall be called
wonderful counsellor,mighty God everlasting Father the king of
kings Emmanueli kaabo o s’aye o

[Bridge]
Araye eyo,araye ejo eyo,ati bi abi olugbala funwa/3X

(Interlude by talking drum)

Call: Alade alafia kaabo o s’aye o
(All): Emmanueli kaabo o s’aye o
Call: Olumoran okan wa kaabo o s’aye o
(All): Emmanueli kaabo o s’aye o
Call: Oba to n fi mimo bora bi aso o kaabo o
(All): Emmanueli kaabo o s’aye o
Call: Olufe okan mi kaabo o s’aye ooooo
(All): Emmanueli kaabo o s’aye o
Call: Olowogbogboro ti n yo’mo re loofin aye kaabo o
(All): Emmanueli kaabo o s’aye o
Call: The lover of our soul kaabo o s’aye oooo
(All): Emmanueli kaabo o s’aye o
Call: Erujeje ni o kaabo o s’aye ooo
(All): Emmanueli kaabo o s’aye o

Leave a Comment