Download Yoo Daa Mp3 by Sola Allyson
Video : Yoo Daa by Sola Allyson
Yoo Daa Lyrics by Sola Allyson
[Chorus]
Ta le ni naa ti n so pe ko le yoo da,
Ta le ni naa ti n so pe aye mi o le dide mo,
Ta le ni naa ti n so pe o ti tan ooooo ahahah
Wo mi ko ripe Oluwa ma dun gan o si po oo

[Verse 1]
Eni to mumi bo lati ipele mi o ma ga
O hun lo mumi rin la la e fe se ko
O ma ga
Ohun lo mumi duro mi o le subu o lai lai
Wo mi ko ripe alanu yi ma ga
Ohun lo da mi bi adaran je Oluso Aguntan mi
Ohun lo n re mi lo n to isise mi beni
Oro re fitila lese mi imole lona mi
Ati pe mi wole imole Baba Beni
[Chorus]
Ta le ni naa ti n so pe ko le yoo da,
Ta le ni naa ti n so pe aye mi o le dide mo,
Ta le ni naa ti n so pe o ti tan ooooo ahahah
Wo mi ko ripe Oluwa ma dun gan o si po oo
Ta le ni naa ti n so pe ko le yoo da,
Ta le ni naa ti n so pe aye mi o le dide mo,
Ta le ni naa ti n so pe o ti tan ooooo ahahah
Wo mi ko ripe Oluwa ma dun gan o si po oo
[Verse 2]

(Adlips x4)